Words that came up at Yoruba Conversation Club – April 2014

Words that came up at Yoruba Conversation Club – April 2014

Ere ku su

Congratulations oriire

Earring afikọti

Reduce dinku

Festival ajọdun
Stairs abagunke / pẹtẹẹsì
So nitoribẹ

Tongue-twister

Mistakes aṣiṣe

Generation iran

Audio iwe ohun

William Boscombe
Lucky oloriire

Concept Erongba / atinuda (intuit)
Pencil ikọwe

Pen ikọwe

In-laws

Sunday ọjọ Sundee

History itan-akọọlẹ

Story alo

Formal aigbafẹ
professional alamọdaju
siblings tegbontaburo

Cousins omoegbon tabi omoaburo

Polygamy ikobirin

get along gba pẹlú

hobby ifisere

since sugbon (igba)

circumstantial okunfa

email imeeli

prompts fọwọ tọ

ingredients eroja

everyday lojojumo

space ààyè

project manager ise agbese faili

industry ile iṣẹ

contract ìwé adehun

mess oro idotin